歌曲 / 歌词

Palongo

Listen on Apple Music

歌词

Isola nígbà kan rí
Ta léni tó sọ pé kò sórín lagodo tiwa
Kosilu lagodo tiwa
Iro le fi pa, eke le fi se
Ọmọ egungunjobi
Terry Apala mo dode
So ń gbó rhythm
Ọmọ isoko ni e
Mo tún gbé jo alarabara kan dé o
Kan mi a jo
Kan yodi seyin o
Palongo lè rí yen
Alajo tán ah
Palongo leri yen
Ajo tadireke
Palongo lè rí yen
Attention, attention
Put on your dancing shoe
Make you dey follow me dance