歌曲 / 歌词

Awo

Listen on Apple Music

歌词

Le-le-le-le-le-le, eyin awo lari
Le-le-le-le-le-le, eyin awo lari
Gbogbo ohun ti ese fun wa
Awon to fe wa odun mo won
Awa o binu enikan
B'eniyan binu enikan omo
Oja oyingbo, ko mope enikan o wa o
B'oko kan o re ejinrin, egbe-gberun re a lo
Sugbon t'aba se won o
Agbagba won a foriji wa o awo
Sugbon t'aba se won o
Agbagba won a foriji wa o awo
Won afori ji wa, agbagba won a fori ji wa o awo
Le-le-le-le-le-le, eyin awo lari
Le-le-le-le-le-le, eyin awo lari
Gbogbo ohun ti ese fun wa
Awon to fe wa odun mo won
Awa o binu enikan, b'eniyan binu enikan omo
Oja oyingbo, ko mope enikan o wa o
B'oko kan o re ejinrin, egbe-gberun re a lo
Sugbon t'aba se won o
Agbagba won a foriji wa o awo
Won aforiji wa o, agbagba won aforiji wa o awo
Won aforiji wa o, agbagba won aforiji wa o awo