歌曲 / 歌词

Ja Funmi

Listen on Apple Music

歌词

Ori mi ye
Jaa ja fun n mi
Eda mi ye o
Jaa ja funmi
Ori Baba mi ori mama mi ye-ye-ye
Jaa ja funmi
Eda mi ye o
Jaa ja funmi
Ori agbe a ja fun agbe
Ori aluko a ja fun o
Ori agbe a ja fun agbe
Ori aluko a ja fun o
Eleda mi maa ma gbagbe mi
O ba maa ma ja o
Agbe lo l'aro ye-ye-ye
Aluko lo ma l'osunsa o
Agbe lo ni ero ye-ye
Aluko lo ma l'osun gelele
Atori l'aye to ba lo siwaju a tun lo seyin ni
Atori l'aye se to ba lo siwaju a tun lo seyin ni
Kolonto ko wa ko wa (kowa kolonto)
Kolonto ko wa ye-ye-ye
(Kowa ko lo n to)
Bo to wu kopolo tobi to (Ile e lo mi a mo)
Bo ti wu kopolo tobi to ye-ye-ye (Ile e lo mi a mo)
Ori mi ye
Jaa ja funmi
Eda mi ye o
Jaa ja funmi
Ori Baba mi ori mama mi dakun ye-ye-ye
Jaa ja funmi
Eda mi ye o
Jaa ja funmi
Ori agbe a ja fun agbe
Ori aluko a ja fun o
Ori agbe a ja fun agbe
Ori aluko a ja fun o
Eleda mi maa ma gbagbe mi
O ba maa ma ja o
Atori l'aye to ba lo siwaju a tun lo seyin ni
Atori l'aye se to ba lo siwaju a tun lo seyin ni
Kolonto ko wa ko wa (kowa kolonto)
Kolonto ko wa ye-ye-ye
(Kowa ko lo n to)
Bo to wu kopolo tobi to (Ile e lo mi a mo)
Bo ti wu kopolo tobi to ye-ye-ye (Ile e lo mi a mo)
Ori agbe a ja fun agbe
Ori aluko a ja fun o
Ori agbe a ja fun agbe
Ori aluko a ja fun o
Eleda mi maa ma gbagbe mi
O ba maa ma ja o
Atori l'aye to ba lo siwaju a tun lo seyin ni
Atori l'aye se to ba lo siwaju a tun lo seyin ni
Kolonto ko wa ko wa (kowa kolonto)
Kolonto ko wa ye-ye-ye
(Kowa kolonto)